Òkú Ààrin-Gbùngbùn
€ 4,99
Kopen bij Amazon Bekijk in Apple BooksLiever op papier? Alle uitvoeringen bij Amazon →
Prijs in Apple Books. Bij Amazon kan die afwijken.
- Verschenen
Beschrijving
Àdó ólóró buburu kan bú jáde ni ile ìtàjà nla kan ni Baghdad, ti o pa pupọ awọn olùrajà ati osisẹ, ti ọpọlọpọ si yarọ.Laipẹ, awọn ẹgbẹ bọmbà olupara-ẹni tuntun di awọn ẹniti awọn ọlọpa meje lagbàáyé nwákiri nitoripe wọn ti di ẹrùjẹjẹ fún ara ilu, ti kò ni i se pẹlu ẹsìn tabi òsèlú.Wọn pe awọn akọsẹmọsẹ ẹrọ ayárabiàsá ti ijọba Ṣháínà ati SAS ti Gẹẹsi lati sèrànwọ, sugbọn njẹ wọn yio le sàwári okùnfà bọmbù tó nsẹlẹ lemọlemọ ki ó tó di wipé ọwọ ara ilu kò ni ká wọn mọ?